Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 16 Oṣù Kínní
Ìrísí
- 2003 – Ọkọ̀-àlọbọ̀ Òfurufú Columbia (fọ́tò) gbéra lọ fún ìránlọṣe STS-107 tí yíò di èyí tó ṣe gbèyìn. Columbia játúká ní ọjọ́ 16 lẹ́yìn náà nígbà tó únpadà wọ Ayé.
- 2006 – Ellen Johnson Sirleaf di Ààrẹ ilẹ̀ Liberia. Òhun ni obìnrin àkọ̀kọ̀ tó jẹ́ dídìbòyàn bíi olórí orílẹ̀-èdè ní Áfríkà.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1901 – Fulgencio Batista, Ààrẹ ilẹ̀ Kúbà (al. 1973)
- 1959 – Sade Adu, ọmọ Yorùbá akọrin ará Brítánì
- 1979 - Aaliyah, akọrin ará Amẹ́ríkà (al. 2001)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1794 – Edward Gibbon, akọ̀wéìtàn ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (ib. 1737)
- 2001 – Laurent-Désiré Kabila, Ààrẹ ilẹ̀ OO Kongo (ib. 1939)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |