Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 11 Oṣù Keje
Ìrísí
- 1804 – Ìjàkadi fàá kí Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà Aaron Burr ó yìnbọn mọ́ Alákóso Ìnáwó tẹ́lẹ̀ Alexander Hamilton. Ó kú lọ́jọ́ kejì.
- 1960 – Idamu Kongo: Orile-ede Katanga (àsìá) yapa kuro lodo orile-ede Kongo.
- 2006 – Awon eniyan 209 parun leyin idigbolu awon bombu ni Mumbai, India.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1888 – Carl Schmitt, amoye ara Jemani (al. 1985)
- 1930 – Harold Bloom, akawe ara Amerika
- 1937 – Pai Hsien-yung, olukowe ara Taiwan
- 1942 - Olu Jacobs, olusere ara Naijiria
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1905 – Muhammad Abduh, adajo ara Egypt (ib. 1849)
- 1974 – Pär Lagerkvist, olukowe ara Swedin (ib. 1891)
- 1989 – Laurence Olivier, osere ara Ilegeesi (ib. 1907)