Jump to content

Nkechi Justina Nwaogu

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Nkechi Justina Nwaogu
Aṣojú Ìpílẹ̀ ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà
In office
Oṣù karún Ọdún 2011 – Oṣù karún Ọdún 2015
ConstituencyÀárín Abia
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí19 Oṣù Kàrún 1956 (1956-05-19) (ọmọ ọdún 68)
Alma materBrunel University
OccupationOlóṣèlú

Nkechi Justina Nwaogu (bíi ní Ọjọ́ ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù karún Ọdún 1956) jẹ́ olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọ́n dìbò yàn wọlé gẹ́gẹ́ bí aṣojú ààrín Abia, ìpínlẹ̀ Abia ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Ó jẹ́ aṣojú ní ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin láti Ọdún 2011 sí 2015 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú People's Democratic Party.[1][2]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]