Jump to content

Liban Abdi Egal

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Liban Abdi Egal
لبنان عبدي إيغال
Ọjọ́ìbíSomalia
Iṣẹ́entrepreneur
TitleAlága First Somali Bank

Liban Abdi Egal (Lárúbáwá: ليبان عبدي إيغال‎) jẹ́ oníṣòwò ọmọ orílẹ̀ ède Somalia. Òun ni olùdásílẹ̀ àti alága First Somali Bank (FSB), ó dá ilé ìfowópamọ́sí yìí kalẹ̀ ní ọdún 2012.[1]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Mulupi, Dinfin (20 June 2012). "Meet the Boss: Liban Abdi Egal, chairman, First Somali Bank". How We Made It In Africa. http://www.howwemadeitinafrica.com/meet-the-boss-liban-abdi-egal-chairman-first-somali-bank/17619/. Retrieved 30 January 2014.