Jhumpa Lahiri
Jhumpa Lahiri | |
---|---|
Jhumpa Lahiri in 2015 | |
Ọjọ́ ìbí | Nilanjana Sudeshna Lahiri 11 Oṣù Keje 1967 London, England |
Iṣẹ́ | Author |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | American |
Alma mater |
|
Ìgbà | 21st century |
Genre | Novel, short story, postcolonial |
Notable works |
|
Notable awards |
|
Website | |
randomhouse.com/kvpa/jhumpalahiri/ |
Nilanjana Sudeshna "Jhumpa" Lahiri[1] (tí wọ́n bí ní July 11, 1967) jẹ́ òǹkọ̀wé ti Indian àti American, tí ó gbajúmọ̀ fún àwọn ìtàn kékeré rẹ̀, ìwé ìtàn-àròsọ àti àròkọ rẹ̀ ní èdè Gẹ̀ẹ́sì àti ní èdè Italy.
À̀tòjọ ìtàn kékeré rẹ̀ ni Interpreter of Maladies (1999) tó gba ẹ̀bùn Pulitzer Prize for Fiction àti ẹ̀bùn PEN/Hemingway Award, ìwé ìtàn-àròsọ rẹ̀, The Namesake (2003), ni ó fàyọ nínú fíìmù àgbéléwò The Namesake.
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Lahiri sí ìlú London, ó sì jẹ́ ọmọbìnrin ti àwọn ará India tó sí lọ sí West Bengal. Ìdílé rẹ̀ kó lọ sí United States nígbà tó wà ní ọmọ-ọdún mẹ́ra; Lahiri máa ń rí ara rẹ̀ bí i ará America, ó sì máa ń sọ pé, "Wọn ò bí mi síbi àmọ́ ó ṣe é ṣe kó jẹ́ bẹ́ẹ̀."[2] Lahiri dàgbà sí Kingston, ní Rhode Island, níbi tí bàbá rẹ̀, ìyẹn Amar Lahiri ti ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i librarian ní University of Rhode Island;[2] ìwé "The Third and Final Continent", ìtàn tó parí Interpreter of Maladies, jẹ́ èyí tó kọ nípa bàbá rẹ̀.[3] Ìyá Lahiri fẹ́ kí àwọn ọmọ òun dàgbà sí mímọ àṣà Bengali, àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ̀ sì máa ń wá wò wọ́n dáadáa ní Calcutta.[4]
Àtòjọ àwọn àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- 1993 – TransAtlantic Award from the Henfield Foundation
- 1999 – O. Henry Award for short story "Interpreter of Maladies"
- 1999 – PEN/Hemingway Award (Best Fiction Debut of the Year) for "Interpreter of Maladies"
- 1999 – "Interpreter of Maladies" selected as one of Best American Short Stories
- 2000 – Addison Metcalf Award from the American Academy of Arts and Letters
- 2000 – "The Third and Final Continent" selected as one of Best American Short Stories
- 2000 – The New Yorker Best Debut of the Year for "Interpreter of Maladies"
- 2000 – Pulitzer Prize for Fiction for her debut "Interpreter of Maladies"
- 2000 – James Beard Foundation's M.F.K. Fisher Distinguished Writing Award for "Indian Takeout" in Food & Wine Magazine
- 2002 – Guggenheim Fellowship
- 2002 – "Nobody's Business" selected as one of Best American Short Stories
- 2008 – Frank O'Connor International Short Story Award for "Unaccustomed Earth"
- 2009 – Asian American Literary Award for "Unaccustomed Earth"
- 2009 – Premio Gregor von Rezzori for foreign fiction translated into Italian for "Unaccustomed Earth" ("Una nuova terra"), translated by Federica Oddera (Guanda)
- 2014 – DSC Prize for South Asian Literature for The Lowland[5]
- 2014 – National Humanities Medal[6]
- 2017 – Pen/Malamud Award
- 2023 – Honorary Doctorate from The American University of Rome in recognition of her extraordinary contribution to literature in English and Italian.[7]
Àtòjọ iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìwé ìtàn-àròsọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- The Namesake. Boston: Houghton Mifflin. 2003.[8]
- The Lowland (2013)
- (in it) Dove mi trovo. Milan: Guanda. 2018. ISBN 978-88-235-2136-0.
- Whereabouts. New York: Knopf. 2021. ISBN 978-0-593-31831-7.[9]
Àwọn ìtàn kékeré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Interpreter of Maladies (1999)
- "A Temporary Matter" (previously published in The New Yorker)
- "When Mr. Pirzada Came to Dine" (previously published in The Louisville Review)
- "Interpreter of Maladies" (previously published in the Agni Review)
- "A Real Durwan" (previously published in the Harvard Review)
- "Sexy" (previously published in The New Yorker)
- "Mrs. Sen's" (previously published in Salamander)
- "This Blessed House" (previously published in Epoch)
- "The Treatment of Bibi Haldar" (previously published in Story Quarterly)
- "The Third and Final Continent"
- Unaccustomed Earth (2008)
- "Unaccustomed Earth"
- "Hell-Heaven" (previously published in The New Yorker)
- "A Choice of Accommodations"
- "Only Goodness"
- "Nobody's Business" (previously published in The New Yorker)
- "Once In A Lifetime" (previously published in The New Yorker)
- "Year's End" (previously published in The New Yorker)
- "Going Ashore"
- "Hema and Kaushik"
- Racconti romani (in Italian). Rome: Guanda. 2022.
- "Il confine" (The Boundary)
- "La riunione" (The Reunion)
- "Le feste di P." (P.s Parties)
- "Casa luminosa" (Luminous House)
- "La scalinata" (The Stairway)
- "Il ritiro" (Withdrawal)
- "La processione" (The Procession)
- I bigliettini (The Cards)
- Dante Alighieri
Àwọn ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Lahiri, Jhumpa (June 10–17, 2013). "Brotherly Love". The New Yorker 89 (17): 70–89. http://www.newyorker.com/magazine/2013/06/10/brotherly-love-2.
- Lahiri, Jhumpa (January-29-2018). "The Boundary" . The New Yorker.
- Lahiri, Jhumpa (February-8-2021). "Casting Shadows" . The New Yorker.
Ewì
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Il quaderno di Nerina (Italian) (2020)
Adálérí-ìtàn-gidi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìwé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- In altre parole (Italian) (2015) (English translation published as In Other Words, 2016)
- Il vestito dei libri (Italian) (English translation published as The Clothing of Books, 2016)
- Translating Myself and Others (2022)
Àròkọ, ìjábọ̀ ìròyìn àti àwọn àfikún mìíràn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- The Magic Barrel: Stories (introduction) by Bernard Malamud, Farrar, Straus and Giroux, July 2003.
- "Cooking Lessons: The Long Way Home" (September 6, 2004, The New Yorker)
- Malgudi Days (introduction) by R.K. Narayan, Penguin Classics, August 2006.
- "Rhode Island" in State by State: A Panoramic Portrait of America edited by Matt Weiland and Sean Wilsey, Ecco, September 16, 2008
- "Improvisations: Rice" (November 23, 2009, The New Yorker)
- "Reflections: Notes from a Literary Apprenticeship" (June 13, 2011, The New Yorker)
- The Suspension of Time: Reflections on Simon Dinnerstein and The Fulbright Triptych edited by Daniel Slager, Milkweed Editions, June 14, 2011.
- Lahiri, Jhumpa (December 7, 2015). Translated from the Italian by Ann Goldstein. "Teach yourself Italian". The New Yorker 91 (39): 30–36. https://www.newyorker.com/magazine/2015/12/07/teach-yourself-italian.[10]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Minzesheimer, Bob. "For Pulitzer winner Lahiri, a novel approach" Archived July 4, 2012, at the Wayback Machine., USA Today, August 19, 2003. Retrieved on 2008-04-13.
- ↑ 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedusa2
- ↑ Flynn, Gillian. "Passage To India: First-time author Jhumpa Lahiri nabs a Pulitzer," Archived December 31, 2008, at the Wayback Machine. Entertainment Weekly, April 28, 2000. Retrieved on 2008-04-13.
- ↑ Aguiar, Arun. "One on One With Jhumpa Lahiri" Archived October 7, 2008, at the Wayback Machine., Pifmagazine.com, July 28, 1999. Retrieved on 2008-04-13.
- ↑ Claire Armitstead (January 22, 2015). "Jhumpa Lahiri wins $50,000 DSC prize for south Asian literature". The Guardian. Archived from the original on January 29, 2015. Retrieved January 22, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "President Obama to Award 2014 National Humanities Medal". National Endowment for the Humanities. September 3, 2015. Archived from the original on January 6, 2017. Retrieved September 4, 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "American University of Rome, lauree honoris causa per Jhumpa Lahiri e Carlo Petrini". La Stampa. May 25, 2023. Archived from the original on May 29, 2023. Retrieved May 29, 2023. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Life lessons to learn from The Namesake by Jhumpa Lahiri| Kaitholil.com". kaitholil.com. Archived from the original on October 9, 2022. Retrieved 2022-08-02. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Whereabouts by Jhumpa Lahiri". Penguin Random House. Archived from the original on May 19, 2022. Retrieved December 26, 2020. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Title in the online table of contents is "In translation".