Ìpínlẹ̀ Rivers
Ìpínlẹ̀ Rivers | ||
---|---|---|
| ||
Nickname(s): | ||
Location of Rivers State in Nigeria | ||
Coordinates: 4°45′N 6°50′E / 4.750°N 6.833°ECoordinates: 4°45′N 6°50′E / 4.750°N 6.833°E | ||
Orílẹ̀-èdè | Nigeria | |
Geopolitical zone | South South | |
Formation | 27 Oṣù Kàrún 1967 | |
Olúìlú | Port Harcourt | |
LGAs | Àdàkọ:Comma separated entries | |
Government | ||
• Body | Government of Rivers State | |
• Gómìnà[2] | Ezenwo Wike (PDP) | |
• Deputy | Ipalibo Banigo (PDP) | |
• Legislature | House of Assembly | |
Area | ||
• Total | 11,077 km2 (4,277 sq mi) | |
Area rank | 26th | |
Population (2006 Census) | ||
• Total | 5,198,716[1] | |
• Rank | 6th | |
• Density | 635.89/km2 (1,646.9/sq mi) | |
Demonym(s) | Riverian | |
GDP (PPP) | ||
• Year | 2007 | |
• Total | $21.07 billion[3] | |
• Per capita | $3,965[3] | |
Time zone | UTC+01 (WAT) | |
postal code | 500001 | |
ISO 3166 code | NG-RI | |
HDI (2018) | 0.642[4] medium · 6th of 37 | |
Website | riversstate.gov.ng |
Ìpínlẹ̀ Rivers tí a tún mọ̀ bíi Rivers, ni ìkan nínú àwọn ìpínlẹ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà 36. Gẹ́gẹ́ bí dátà ìkanìyàn tó jáde ní ọdún 2006 ṣe fihàn, ìpínlẹ̀ náà ní iye ènìyàn 5,198,716, èyí sọ ọ́ di ìpínlẹ̀ tó ní iye èniyàn púpọ̀jùlọ kẹfà ní Nàìjíríà.[5] Olúìlú àti ìlú tótóbijùlọ rẹ̀ ni Port Harcourt. Ìlú Port Harcourt ní Nàìjíríà gẹ́gẹ́bí gbọ̀ngàn àwọn ilé-iṣẹ́ epo. Ìpínlẹ̀ Rivers jámọ́ Òkun Atlantiki ní gúúsù, ó ní bodè mọ́ àwọn ìpínlẹ̀ Imo and Abia ní àríwá, ìpílẹ̀ Akwa Ibom ní ìlàòrùn, àti àwọn ìpínlẹ̀ Bayelsa àti Delta ní ìwọ̀òrùn. Ìpínlẹ̀ Rivers ní ọ̀pọ̀ ẹ̀yà tí nínú wọn ni: àwọn Ikwerre, àwọn Ijaw, àwọn Ògóni àti àwọn ẹ̀yà púpọ̀ míràn. Orúkọ fún àwọn ará ìpínlẹ̀ yìí ni "Riverians" tàbi "àwọn ará Rivers".[6]
Apá inú ìpínlẹ̀ náà jẹ́ ẹgàn tútù olóoru.
Ítàn Ìdásílẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìpínlẹ̀ Rivers gba orúkọ rè nípase awọn odò ti o la kojá.
Ijọba Ìbílẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Rivers jẹ́ mẹ́tàlẹ́lógún tí alága ìbílẹ̀ n se akoso gbogbo ìbílè na:
Orúkọ Ijọba Ìbílẹ̀ | Agbègbè(km2) | Census 2006 population |
Ijoko ìṣàkóso | Postal Code |
Wọ́dù |
---|---|---|---|---|---|
Port Harcourt | 109 | 541,115 | Port Harcourt | 500 | 20 |
Obio-Akpor | 260 | 464,789 | Rumuodumaya | 500 | 17 |
Okrika | 222 | 222,026 | Okrika | 500 | 12 |
Ogu–Bolo | 89 | 74,683 | Ogu | 500 | 12 |
Eleme | 138 | 190,884 | Nchia | 501 | 10 |
Tai | 159 | 117,797 | Sakpenwa | 501 | 10 |
Gokana | 126 | 228,828 | Kpor | 501 | 17 |
Khana | 560 | 294,217 | Bori | 502 | 19 |
Oyigbo | 248 | 122,687 | Afam | 502 | 10 |
Opobo–Nkoro | 130 | 151,511 | Opobo Town | 503 | 11 |
Andoni | 233 | 211,009 | Ngo | 503 | 11 |
Bonny | 642 | 215,358 | Bonny | 503 | 12 |
Degema | 1,011 | 249,773 | Degema | 504 | 17 |
Asari-Toru | 113 | 220,100 | Buguma | 504 | 13 |
Akuku-Toru | 1,443 | 156,006 | Abonnema | 504 | 17 |
Abua–Odual | 704 | 282,988 | Abua | 510 | 13 |
Ahoada West | 403 | 249,425 | Akinima | 510 | 12 |
Ahoada East | 341 | 166,747 | Ahoada | 510 | 13 |
Ogba–Egbema–Ndoni | 969 | 284,010 | Omoku | 510 | 17 |
Emohua | 831 | 201,901 | Emohua | 511 | 14 |
Ikwerre | 655 | 189,726 | Isiokpo | 511 | 13 |
Etche | 805 | 249,454 | Okehi | 512 | 19 |
Omuma | 170 | 100,366 | Eberi | 512 | 10 |
Awọn èdè
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aboriginal language dialects | ònkà awọn ti wọn n sọ èdè náà |
---|---|
Abua | 25,000 |
Agbirigba | 30 |
Baan | 50,000 |
Biseni | 4,800 |
Defaka | 200 |
Degema | 30,000 |
Ekpeye | 30,000 |
Eleme | 150,000 |
Engenni | 20,000 |
Ijaw | 200,000 |
Ikwerre | 200,000 |
Kalabari | 570,000 |
Kugbo | 2,000 |
Nkoroo | 4,600 |
O’chi’chi’ | — |
Obolo | 250,000 |
Obulom | 3,420 |
Odual | 18,000 |
Ogba | 80,000 |
Ogbogolo | 10,000 |
Ogbronuagum | 12,000 |
Khana | 500,000 |
Okodia | 3,600 |
Oruma | 5,000 |
Tee | 100,000 |
Ukwuani-Aboh-Ndoni | 50,000 |
Awọn orísìrísí èdè tí ó wa ní ìpínlè Rivers nítítò Ijọba ìbílẹ̀ ìpínlè Rivers:[7]
LGA | Languages |
---|---|
Abua-Odual | Kugbo; Odual; Ogbia, Ijaw |
Ahoada East | Igbo, Ekpeye |
Ahoada West | Egenni, ijaw |
Akuku Toru | Kalabari, Bille |
Andoni | Obolo |
Asari-Toru | Kalabari |
Degema | Abua; Degema; Kalabari; Ogbronuagum; Bille |
Bonny | ibani;Ndoki(igbo) |
Eleme | Eleme; Nchia; Odido; Baan |
Emuohua | igbo |
Etche | Obulom-ochichi; Igbo |
Gokana | Baan; Gokana |
Ikwerre | Ikwerre(igbo) |
Khana | Khana, Baan |
Obio-Akpor | Ikwerre (igbo) |
Ogba-Egbema-Ndoni | Igbo |
Ogoni | Kana, Gokana, Tee, Eleme, Baan |
Ogu-Bolo | Kirike |
Ohaji-Egbema Ndoni | Igbo |
Okrika | Kirike, Igbo |
Opobo-Nkoro | Ibani; Igbo, Defaka; ; Nkoroo |
Oyigbo | Igbo, Baan, Kana |
Port Harcourt | obulom; Ikwerre; Kalabari Kirike; Eleme; Kana; Ijaw; Bille; Gokana; Baan; Igbo |
Omumma | Igbo |
Tai | Tee; Baan |
others | Abureni |
Èkó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ilé ẹ̀kọ́ alakobere àti girama
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Títí di ọdún 1999, ìpínlẹ̀ na ni ile-ẹkọ alakobere bí 2,805 áti ti girama bi 243 tó jẹ́ ti ijọba.
Ilé ẹ̀kọ́ gíga
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Captain Elechi Amadi Polytechnic[8]
- Eastern Polytechnic
- Federal College of Education (Technical), Omoku.
- Ignatius Ajuru University tí ó wà ní Rumuolumeni, Nkpolu Oroworukwo and Ndele.
- Kenule Beeson Saro-Wiwa Polytechnic
- PAMO University of Medical Sciences,Elelenwo, Port Harcourt
- Rivers State University.
- University of Port Harcourt,[9] Choba.
- Ken Saro Wiwa Polytechnic at Bori.
- School of Health Technology, Port Harcourt
- School of Nursing and Midwifery, Rumueme, Port Harcourt.[10]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "2006 PHC Priority Tables – NATIONAL POPULATION COMMISSION". population.gov.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-10-10. Retrieved 2017-10-10.
- ↑ See List of Governors of Rivers State for a list of prior governors
- ↑ 3.0 3.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". EIU Canback. Retrieved 2008-08-20.
- ↑ "Sub-national HDI - Area Database - Global Data Lab". hdi.globaldatalab.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-09-13.
- ↑ "Nigeria: Administrative Division". City Population. Retrieved 28 November 2014.
- ↑ "Rivers State government website". Archived from the original on January 30, 2019. Retrieved December 7, 2010.
- ↑ "Nigeria". Ethnologue. https://www.ethnologue.com/country/NG.
- ↑ "Rivers State College of Arts and Science". Rivers State College of Arts and Science. Archived from the original on 2018-10-17. Retrieved 2010-03-04.
- ↑ "University of Port Harcourt". University Port Harcourt Student Rivers.
- ↑ "SOCIAL INFRASTRUCTURE". OnlineNigeria. 2003-02-10. Retrieved 2010-03-04.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |