Arese Emokpae
Agharese Emokpae (tí wọ́n bí ní January 13, 1988) tí wọ́n mọ̀ sí A'rese jẹ́ òṣèrébìnrin, akọrin àti òǹkàtàn ọmọ Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ nígbà tí ó kópa nínú fíìmù Bolanle Austen-Peters' Terra Kulture, tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Wakaa: The Musical, èyí sì mu kópa nínú ìdíje The Voice Nigeria, tó sì jáwé olúborí.[1] Ní ọdún 2017 ó di gbajúgbajà fún ìkópa rẹ̀ bí i Senami Minasu nínú fíìmù Africa Magic tí àkọ́lé rẹ̀ ń jé Jemeji. Lọ́dún yẹn náà ni ó ṣe àgbéjáde orin rẹ̀ àkọ́kọ́, tó pè ní "Uwe No".[2]
Ìpìlẹ̀ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Inú iṣẹ́-ọnà ni wọ́n bí A'rese sí. Bàbá-bàbá rẹ̀ ni gbajúgbajà ayàwòrán àti agbẹ́gilére tí orúkọ rè ń jẹ́ Erhabor Emokpae.
Ètò-ẹ̀kọ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A'rese lọ ilé-ìwé Washington and Lee University níbi tí ó tí kúndùn orin kíkọ àti ijó. Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè Bachelor of Arts nínú ẹ̀kọ́ Visual Art, tó sì dojú lé Printmaking. Lẹ́yìn tí ó kópa gẹ́gẹ́ bí i "Velma Kelly" nínú fíìmù Broadway musical Chicago, ó pinnu láti tẹ̀síwájú nínú iṣẹ́ eré-ṣíṣe.[3] Láti ìgbà tó kẹ́kọ̀ọ́ jáde ní ọdún 2010 ni ó ti mú iṣẹ́ yìí gẹ́gẹ́ bí èyí tó yàn.
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Emokpae bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ ní Chicago, Illinois[4]. Púpọl lára àwọn ẹ̀dá-ìtàn tó ṣe ní tíátà náà ni The Fairy Godmama nínú fíìmù The Other Cinderella[5] àti Mya nínú One Name Only.[6] Lẹ́yìn tó ṣiṣẹ́ níbẹ̀ fún ọdún mẹ́ta, ó pinnu láti kó wá́ sí Èkó, ní Nàìjíríà láti wà ṣe iṣẹ̀ náà ni pẹrẹu.
Ní ọdún 2014, ó kópa nínú àgbéjáde BAP, ìyẹn Saro: the Musical 2.[7] Ó tún farahàn gẹ́gẹ́ bí i Kike Johnson nínú fíìmù àwọn BAP/Terra Kulture stable, ìyẹn Wakaa: The Musical[8].
Ní ọdún 2016, Emokpae gbìyànjú láti kópa nínú ètò The Voice Nigeria. Lára àwọn orin tó kọ ní Skyfall àti Hallelujah. Ó gbégbá orókè pẹ̀lú Chike.[9]
Lẹ́yìn àṣeyọrí yìí, Emokpae tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Universal Music Group; níbi tí ó ti ṣá̀gbéjáde orin rẹ̀ àkọ́kọ́, ìyẹn Uwe No.[10]
Ní ọdún 2017, ó kópa nínú fíìmù Jemeji gẹ́gẹ́ bí i Senami Minasu. Ó sì tún kópa nínú fíìmù EbonyLife TV kan, ìyẹn "MMM".[11]
Àwọn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Orí ẹ̀rọ-amóhùnmáwòrán
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Network | Role | Notes |
---|---|---|---|---|
2016 | The Voice Nigeria | Africa Magic | Self | Reality Show |
Babysitting Ejiro | Kemi | Television movie | ||
2016-2017 | Tinsel | Bisola | Unknown # of episodes | |
2017-2018 | Jemeji | Senami Minasu | 260 episodes | |
2021 | M.M.M. | LacedUp Productions | Marion | Web Series |
Tíátà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Show | Role | Notes |
---|---|---|---|
2012 | The Marvin Gaye Story | Mary Wells/Ensemble | Black Ensemble Theater; Chicago, IL |
One Name Only | Mya | ||
The Other Cinderella | Fairy Godmamma | ||
2013 | Once Upon A People | The Storyteller | |
She Kills Monsters | Vera (u/s) | Buzz22 Chicago at Steppenwolf; Chicago, IL | |
2014-2015 | Saro: The Musical 2 | Rume | BAP Productions/Terra Kulture |
2015 | Wakaa: The Musical | Kike Johnson |
Àwọn orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdákọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Song Title | Artist | Album |
---|---|---|---|
2017 | "Uwe No" | A'rese ft. LadiPoe | Uwe No - Single |
2018 | "Beautiful" | A'rese | Beautiful - Single |
Àjọṣepọ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Song Title | Artist | Album |
---|---|---|---|
2017 | "Out Of My League" | Dominic Neill ft. A'rese | Out Of My League |
"#WCW" | Kalen Lumiere ft. A'rese | Realistic Love | |
"Birds 'n' Bees" |
Àmì-ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Award | Category | Film | Result | Ref |
---|---|---|---|---|---|
2019 | Best of Nollywood Awards | Best Actress in a Lead role –English | Unbreakable | Wọ́n pèé | [12] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "A'rese WINS Season 1 of The Voice Nigeria - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2018-10-02.
- ↑ Solanke, Abiola. "A'rese - Uwe Uno feat Ladi Poe" (in en-US). https://www.pulse.ng/entertainment/music/arese-uwe-uno-feat-ladi-poe-id6252755.html.
- ↑ "A’rese Emokpae '10 Wins "The Voice Nigeria"" (in en-US). The Columns. 2016-07-15. https://columns.wlu.edu/arese-emokpae-10-wins-the-voice-nigeria/.
- ↑ "A’rese Emokpae : Chicago Theater Beat". chicagotheaterbeat.com. Archived from the original on 2018-10-01. Retrieved 2018-10-02.
- ↑ "Review: The Other Cinderella (Black Ensemble Theatre) : Chicago Theater Beat". chicagotheaterbeat.com. Archived from the original on 2018-10-02. Retrieved 2018-10-02.
- ↑ Jones, Chris. "At BET, a tuneful show with new names to know" (in en-US). chicagotribune.com. http://www.chicagotribune.com/ct-ent-1010-one-name-review-20121009-column.html.
- ↑ "Again, Saro 2 To Thrill A Easter" (in en-US). Archived from the original on 2020-09-16. https://web.archive.org/web/20200916174936/https://guardian.ng/features/weekend/again-saro-2-to-thrill-a-easter/.
- ↑ "PHOTOS- Bolanle Austen-Peters Thrills Again with Wakaa The Musical - ASIRI Magazine" (in en-US). ASIRI Magazine. 2015-12-31. Archived from the original on 2018-10-02. https://web.archive.org/web/20181002181214/http://asirimagazine.com/en/photos-bolanle-austen-peters-thrills-again-with-wakaa-the-musical/.
- ↑ Bawse, Jay (2016-08-01). "Welcome To Fashion Uncut Media: A’rese WINS Season 1 of The Voice Nigeria". Welcome To Fashion Uncut Media. Retrieved 2018-10-02.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:02
- ↑ "EbonyLife TV on Instagram: "That moment when the sound mixer @taiwo.akiode and @kamhair_ came up with the brilliant idea to hide the wireless Lavalier microphone…"". Instagram (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-12-26. Retrieved 2018-10-02.Àdàkọ:Cbignore
- ↑ Bada, Gbenga (2019-12-15). "BON Awards 2019: 'Gold Statue', Gabriel Afolayan win big at 11th edition". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 15 December 2019. Retrieved 2021-10-10. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)