Adeyemi Afolahan
Ìrísí
Adeyemi Ambrose Afolahan | |
---|---|
Alábójútó àkọ́kọ́ ìpínlẹ̀ Taraba | |
In office Ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n Oṣù kẹjọ Ọdún 1991 – Ọjọ́ kejì Oṣ̀ù kínín Ọdún 1992 | |
Asíwájú | Abubakar Salihu (Gongola State) |
Arọ́pò | Jolly Nyame |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 26 Oṣù Kejìlá 1949 Ibadan, Oyo State, Nigeria |
Adeyemi Afolahan (bíi Ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n Oṣù kejìlá Ọdún 1947) jẹ́ alábójútó àkọ́kọ́ ìpínlẹ̀ Taraba, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Wọ́n yàán ní ọdún 1991 lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n dá ìpínlẹ̀ Taraba sílẹ̀.[1][2][3]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nigerian States". WorldStatesmen. Archived from the original on 28 May 2010. Retrieved 2010-05-28.
- ↑ Pita Ochai and Gift Uwaezuoke (6 December 2009). "In the News". Retrieved 2010-05-28.
- ↑ Mathias Oko (30 May 2000). "Navy top brass joins in the campaign against AIDS". Newswatch. Retrieved 2010-05-28.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |