Jump to content

Oyin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àtúnyẹ̀wò ní 10:21, 12 Oṣù Ọ̀wàrà 2024 l'átọwọ́ Agbalagba (ọ̀rọ̀ | àfikún)
(ìyàtọ̀) ← Àtúnyẹ̀wò tópẹ́ju | Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí (ìyàtọ̀) | Àtúnyẹ̀wò tótuntunju → (ìyàtọ̀)

Àdàkọ:Other uses Àdàkọ:Pp

A jar of honey with a honey dipper and an American biscuit

Oyin ni ó jẹ́ ohun àdídùn olómi tí ìrísí rẹ̀ kìí ṣàn bí omi tí àwọn kòkòrò oyin oríṣiríṣi ma ń pèsè.[1][2] Kòkòrò oyin ni wọ́n ma ń kórajọ pọ̀ tí wọ́n ma ń ya orísiríṣi oje tí wón bá rí fà mu lára orísiríṣi ọ̀mùnú ewé òdòdó àti igi tí wọ́n bá ti mu. Àwọn ohun tínwón ti fàmu yìí ni wọ́n ma ń pọ̀ jáde láti ẹnu wọn padà sínú ilé wọn tí wọ́n ń pe ní afárá.


Àwọn ìtọ́kasí

  1. Crane, Eva (1990). "Honey from honeybees and other insects". Ethology Ecology & Evolution 3 (sup1): 100–105. doi:10.1080/03949370.1991.10721919. ISSN 0394-9370. 
  2. Grüter, Christoph (2020). Stingless Bees: Their Behaviour, Ecology and Evolution. Fascinating Life Sciences. Springer New York. doi:10.1007/978-3-030-60090-7. ISBN 978-3-030-60089-1. https://link.springer.com/book/10.1007%2F978-3-030-60090-7#toc. Retrieved 27 May 2021.