Jump to content

Bálíníìsì

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Bátíníìsì

Balinese

Omo egbé ebí èdè Austronesian ni èdè yìí. Àwon tí ó n so ó féréè tó mílíònù mérin (3.8 million) ní erékùsù Báálì (Bali) ní In-indoníísíà (Indonesia). Àkotó Bálíníìsì àti ti Rómáànù (Balinese and Roman alphabet)ni wón fi ń ko èdè yìí sílè.