Jump to content

Mutiu Adepoju

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Mutiu Adepoju
Mutiu Adepoju
Nípa rẹ̀
OrúkọMutiu Adepoju
Ọjọ́ ìbí22 Oṣù Kejìlá 1970 (1970-12-22) (ọmọ ọdún 54)
Ibùdó ìbíIbadan, Nigeria
Ìga1.80 m (5 ft 11 in)
IpòMidfielder
Èwe
1986–1987Femo Scorpions
Alágbàtà*
OdúnẸgbẹ́Ìkópa(Gol)
1988Shooting Stars
1989Julius Berger
1989–1992Real Madrid B65(27)
1992–1996Racing Santander123(24)
1996–2000Real Sociedad89(8)
2000–2001Al-Ittihad
2001–2002Salamanca14(0)
2002–2003Samsunspor8(0)
2003–2004AEL Limassol5(1)
2004–2005Eldense
2005–2006CD Cobeña
Agbábọ́ọ̀lù ọmọorílẹ̀-èdè
1990–2002Nigeria54(5)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Mùtíù Adépòjù, eni tí ojó ìbí rè jé 22 Oşù Kejìlá (ojó kejìlélógún Oşù Òpe) 1970, tí a sì bí sí'lù ú Ìbàdàn, jé agbábóòlù-elésè (bóòlù àfesègbá) fún orílè-èdè rè, Nàìjíríà.