Jump to content

Gàbọ̀n

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Gàbọ̀n
Gabonese Republic

République Gabonaise
Motto: "Union, Travail, Justice"
(Faransé fún "Ìṣọ̀kan, Iṣẹ́, Ìdájọ́")
Orin ìyìn: La Concorde
The Concord
Location of Gàbọ̀n
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
Libreville
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench
Vernacular languagesFang, Myene
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn
(2000)
Fang 28.6%
Punu 10.2%
Nzebi 8.9%
French 6.7%
Mpongwe 4.1%
other Africans
and Europeans 154,000
(including 10,700 French and 11,000 persons of dual nationality)
Orúkọ aráàlúGabonese, Gabonaise
ÌjọbaOrílẹ̀-èdè olómìnira oníààrẹ
• Ààrẹ
Brice Oligui
Raymond Ndong Sima
AṣòfinIléaṣòfin
Ilé Alàgbà
Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin
Independence
• from France
August 17, 1960
Ìtóbi
• Total
267,667 km2 (103,347 sq mi) (76th)
• Omi (%)
3.76%
Alábùgbé
• 2009 estimate
1,475,000[1] (150th)
• Ìdìmọ́ra
5.5/km2 (14.2/sq mi) (216th)
GDP (PPP)2011 estimate
• Total
$24.571 billion[2]
• Per capita
$16,183[2]
GDP (nominal)2011 estimate
• Total
$16.176 billion[2]
• Per capita
$10,653[2]
HDI (2010) 0.648[3]
Error: Invalid HDI value · 93rd
OwónínáCentral African CFA franc (XAF)
Ibi àkókòUTC+1 (WAT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (not observed)
Ojúọ̀nà ọkọ́right
Àmì tẹlifóònù241
Internet TLD.ga

Gàbọ̀n (play /ɡəˈbɒn/; ìpè Faransé: ​[ɡabɔ̃]), lonibise bi Orile-ede Olominira ara Gabon (Faransé: République Gabonaise) je orile-ede ni iwoorun gbongan Afrika to ni bode mo Guinea Alagedemeji ni ariwaiwoorun, Cameroon ni ariwa, ati mo Orile-ede Olominira ile Kongo to lopo ni ilaorun ati guusu. Ikun-omi Guinea, apa Okun Atlantiki si iwoorun. Ile re tobi to 270,000 km² o si ni alabugbe to to 1,500,000. Oluilu ati ilu totobijulo re ni Libreville.

Lati igba ilominira latowo Fransi ni August 17, 1960, awon aare meta loti joba ni Gabon. Ni arin ewadun 1990, Gabon bere sistemu egbe oloselu pupo ati isepo oloselu tuntun to fi aye gba igbese aladiboyan kedere to si satunse opo awon ise ijoba. Gabon ti je omo-egbe alaije tigba gbogbo ni Igbimo Abo UN fun igba 2010-2011.

Low Isupo alabugbe kekere lapapo mo opo awon ohun alumoni ati idawosi aladani okere ti so Gabon di ikan ninu awon orile-ede to jomitoro julo ni Afrika, pelu HDI to gajulo[4] ati GDP ti enikookan togajulo keta (PPP) (leyin Equatorial Guinea ati Botswana) ni agbegbe yi.



  1. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Gabon". International Monetary Fund. Retrieved 2012-04-18. 
  3. "Human Development Report 2010" (PDF). United Nations. 2010. Retrieved 5 November 2010. 
  4. "Human Development Report 2011 - Human development statistical annex" (PDF). HDRO (Human Development Report Office United Nations Development Programme. pp. 127–130. Retrieved 2 November 2011.