Jump to content

Adewale Akinnuoye-Agbaje

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Adewale Akinnuoye-Agbaje
Akinnuoye-Agbaje ní 2013
Ọjọ́ìbí22 Oṣù Kẹjọ 1967 (1967-08-22) (ọmọ ọdún 57)
London, England
Orúkọ mírànAdewalé, Triple A
Iléẹ̀kọ́ gígaKing's College London
University of London International Programme
Iṣẹ́Actor
Ìgbà iṣẹ́1994–present

Adewale Akinnuoye-Agbaje (Yo-Adewale Akinnuoye-Agbaje.ogg listen; tí a bí ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹjọ ọdún 1967) jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bi Simon Adebisi nínú eré Oz, Mr. Eko nínú Lost, Lock-Nah nínú The Mummy Returns, Nykwana Wombosi nínú The Bourne Identity, Heavy Duty nínú G.I. Joe: The Rise of Cobra, Kurse nínú Thor: The Dark World, Killer Croc nínú Suicide Squad, Malko nínú Game of Thrones,[1] Dave Duerson nínú Concussion,[2] àti Ogunwe nínú His Dark Materials.[3]

Eré àkọ́kọ́ tí Akinnuoye-Agbaje's dárí ni Farming,[4] wrapped production in 2017[5].

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Lawler, Kelly (17 October 2014). "He was also in get rich or die trying'Lost' alum joins 'Game of Thrones' as ... someone". USA Today. http://entertainthis.usatoday.com/2014/10/17/game-of-thrones-adewale-akinnuoye-agbaje/. 
  2. White, James (28 October 2014). "Adewale Akinnuoye-Agbaje Joins NFL Concussion Drama". EmpireOnline. https://www.empireonline.com/news/story.asp?NID=42594. 
  3. "His Dark Materials (TV Series 2019–2022)". IMDb. Retrieved 2022-12-21. 
  4. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named konbini
  5. McNary, Dave (2 November 2017). "First Look at Kate Beckinsale, Gugu Mbatha-Raw's British Drama 'Farming'". Variety. Retrieved 6 October 2018.