Jump to content

Rita Nwadike

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The printable version is no longer supported and may have rendering errors. Please update your browser bookmarks and please use the default browser print function instead.
Rita Nwadike
Personal information
Ọjọ́ ìbí3 Oṣù Kọkànlá 1974 (1974-11-03) (ọmọ ọdún 49)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga1.54m
Playing positionMidfielder
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2004Rivers Angels
National team
2004Nigeria women's national football team14(0)
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Rita Nwadike jẹ ọkan lara awọn agbabọọlu lobinrin orilẹ ede Naigiria tẹlẹ ti a bini 3, óṣu November ni ọdun 1974. Àrabinrin naa ti ṣere fun team awọn agbabọọlu Obirin Naigiri ti national ni olympic ọdun 2004[1].

Aṣeyọri

  • Rita lo kọkọ scorẹ goal fun órilẹ ede Naigiri ni Cup FIFA awọn obinrin agbaye ninu idije to waye ni sweden ni ọdun 1995[2][3].
  • Rita ati awọn akẹgbẹ rẹ kopa ninu quarter finals ti Cup FIFA awọn obinrin agbaye to waye ni ilẹ america ni ọdun 1999, lẹyin ọdun mejilelogun ni awọn elere yii gba ami ẹyẹ fun àṣeyọri naa to waye ni Victoria Island ni ilu Eko[4][5].

Itọkasi

  1. https://www.eurosport.com/football/rita-nwadike_prs414602/person.shtml
  2. https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensworldcup/sweden1995/teams/1882893
  3. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2021-05-06. Retrieved 2022-05-26. 
  4. https://www.thisdaylive.com/index.php/2021/09/20/22-years-after-nff-to-honour-super-falcons-class-of-1999/
  5. https://thewillnigeria.com/news/nff-honours-super-falcons-class-of-1999-at-nff-aiteo-awards-ceremony/