Jump to content

Cholera: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
kNo edit summary
kNo edit summary
Ìlà 1: Ìlà 1:




'''Àìsàn Kọ́lẹ́rà''' tabí '''Àìsàn onígbáméjì''' ({{IPAc-en|'|k|ɒ|l|ər|ə}}) jẹ́ [[Àrùn|àrùn]] tàbí àìsàn tí ó ma ń ràn tí ó lè kọlu [[Eniyan|ènìyàn]] nígbà tí kòkòrò àrùn [[baktéríà]] kan tí wọ́n ń pè ní ''[[Vibrio cholerae]]'' bá kọlu [[ìfun]] kékeré tí ó ń gba [[Oúnjẹ]] dúró lára ènìyàn.<ref name="Fink2016">{{cite book|last1=Finkelstein|first1=Richard A.|chapter=Cholera, ''Vibrio cholerae'' O1 and O139, and Other Pathogenic Vibrios|pmid=21413330|id={{NCBIBook2|NBK8407}}|editor1-last=Baron|editor1-first=Samuel|title=Medical Microbiology|date=1996|publisher=University of Texas Medical Branch at Galveston|isbn=978-0-9631172-1-2|edition=4th}}</ref><ref name="CDC2015Pro">{{cite web|title=Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals|url=https://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|publisher=[[Centers for Disease Control and Prevention]]|access-date=17 March 2015|date=January 6, 2015|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20150320052724/http://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|archive-date=20 March 2015}}</ref> Àìsàn yí lè tètè farahàn lára eni tí ó bá mú tàbí kí ìfarahàn rẹ̀ mọ níwọ̀nba, bákan náà sì ni ìfarahàn àìsàn náà lè mú ọwọ́ èle pẹ̀lú.<ref name="CDC2015Pro2">{{cite web|title=Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals|url=https://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|publisher=[[Centers for Disease Control and Prevention]]|access-date=17 March 2015|date=January 6, 2015|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20150320052724/http://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|archive-date=20 March 2015}}</ref> Àmọ́, bí àìsàn yí bá mọ́wọ́ èle, aláàrẹ̀ náà yóò ma yàgbẹ́ gbuuru fún [[ọjọ́]] mélòó kan. Bákan náà ni onítọ̀hún tún lè má a bì tí gbogbo inú rẹ̀ yóò sì má a lọ́ ọ jáì jáí.<ref name="CDC2015Pro2" /> Bí [[Èébì|èébì]] tàbí [[Ìgbẹ́ Ènìyàn|ìgbẹ́]] aláàrẹ̀ náà báwá pọ̀ lápọ̀jù, èyí lè mú kí ipò tí [[omi]] wà nínú àgọ́ ara rẹ̀ ó dínkù kọjá ààlà, okun inú rẹ̀ kò sì ní gbé kánkán mọ́ láàrín wákàtí péréte tí ó fi ń bì tàbí ṣègbọ̀nsẹ̀. Ìgbọ̀nsẹ̀ gbuuru yíyà yí lè mú kí [[ojú]] aláàrẹ́ náà ó jìn wọnú láìpẹ́. Òtútù àbaadì lè ma mú u pẹ̀lú, [[iṣan]] ara rẹ̀ yóò ma lẹ, bákan náà ni àwọ̀ ara rẹ̀ yóò ma hunjọ pẹ̀lú. <ref name="Lancet2012">{{cite journal|vauthors=Harris JB, LaRocque RC, Qadri F, Ryan ET, Calderwood SB|title=Cholera|journal=Lancet|volume=379|issue=9835|pages=2466–2476|date=June 2012|pmid=22748592|pmc=3761070|doi=10.1016/s0140-6736(12)60436-x}}</ref> Àìtó omi ara aláàrẹ̀ mọ́ yìí lè mú kí àwọ̀ rẹ̀ yí padà sí àwọ̀ búlúù.<ref>{{cite book|last1=Bailey|first1=Diane|title=Cholera|date=2011|publisher=Rosen Pub.|location=New York|isbn=978-1-4358-9437-2|page=7|edition=1st|url=https://books.google.com/books?id=7rvLPx33GPgC&pg=PA7|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20161203190215/https://books.google.com/books?id=7rvLPx33GPgC&pg=PA7|archive-date=2016-12-03}}</ref> Lọ́pọ̀ ìgbà tí àìsàn yí bá kọlu ènìyàn, ó ma ń to wákàtí méjì sí ọjọ́ márùn ún kí àpẹẹrẹ rẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀ sí í farahàn lára ènìyàn. .
'''Àìsàn Kọ́lẹ́rà''' tabí '''Àìsàn onígbáméjì''' ({{IPAc-en|'|k|ɒ|l|ər|ə}}) jẹ́ [[Àrùn|àrùn]] tàbí àìsàn tí ó ma ń ràn tí ó lè kọlu [[Eniyan|ènìyàn]] nígbà tí kòkòrò àrùn [[baktéríà]] kan tí wọ́n ń pè ní ''[[Vibrio cholerae]]'' bá kọlu [[ìfun]] kékeré tí ó ń gba [[Oúnjẹ]] dúró lára ènìyàn.<ref name="Fink2016">{{cite book|last1=Finkelstein|first1=Richard A.|chapter=Cholera, ''Vibrio cholerae'' O1 and O139, and Other Pathogenic Vibrios|pmid=21413330|id={{NCBIBook2|NBK8407}}|editor1-last=Baron|editor1-first=Samuel|title=Medical Microbiology|date=1996|publisher=University of Texas Medical Branch at Galveston|isbn=978-0-9631172-1-2|edition=4th}}</ref><ref name="CDC2015Pro">{{cite web|title=Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals|url=https://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|publisher=[[Centers for Disease Control and Prevention]]|access-date=17 March 2015|date=January 6, 2015|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20150320052724/http://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|archive-date=20 March 2015}}</ref> Àìsàn yí lè tètè farahàn lára eni tí ó bá mú tàbí kí ìfarahàn rẹ̀ mọ níwọ̀nba, bákan náà sì ni ìfarahàn àìsàn náà lè mú ọwọ́ èle pẹ̀lú.<ref name="CDC2015Pro2">{{cite web|title=Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals|url=https://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|publisher=[[Centers for Disease Control and Prevention]]|access-date=17 March 2015|date=January 6, 2015|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20150320052724/http://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|archive-date=20 March 2015}}</ref> Àmọ́, bí àìsàn yí bá mọ́wọ́ èle, aláàrẹ̀ náà yóò ma yàgbẹ́ gbuuru fún [[ọjọ́]] mélòó kan. Bákan náà ni onítọ̀hún tún lè má a bì tí gbogbo inú rẹ̀ yóò sì má a lọ́ ọ jáì jáí.<ref name="CDC2015Pro2" /> Bí [[Èébì|èébì]] tàbí [[Ìgbẹ́ Ènìyàn|ìgbẹ́]] aláàrẹ̀ náà báwá pọ̀ lápọ̀jù, èyí lè mú kí ipò tí [[omi]] wà nínú àgọ́ ara rẹ̀ ó dínkù kọjá ààlà, okun inú rẹ̀ kò sì ní gbé kánkán mọ́ láàrín wákàtí péréte tí ó fi ń bì tàbí ṣègbọ̀nsẹ̀. Ìgbọ̀nsẹ̀ gbuuru yíyà yí lè mú kí [[ojú]] aláàrẹ́ náà ó jìn wọnú láìpẹ́. Òtútù àbaadì lè ma mú u pẹ̀lú, [[iṣan]] ara rẹ̀ yóò ma lẹ, bákan náà ni àwọ̀ ara rẹ̀ yóò ma hunjọ pẹ̀lú. <ref name="Lancet2012">{{cite journal|vauthors=Harris JB, LaRocque RC, Qadri F, Ryan ET, Calderwood SB|title=Cholera|journal=Lancet|volume=379|issue=9835|pages=2466–2476|date=June 2012|pmid=22748592|pmc=3761070|doi=10.1016/s0140-6736(12)60436-x}}</ref> Àìtó omi ara aláàrẹ̀ mọ́ yìí lè mú kí àwọ̀ rẹ̀ yí padà sí àwọ̀ búlúù.<ref>{{cite book|last1=Bailey|first1=Diane|title=Cholera|date=2011|publisher=Rosen Pub.|location=New York|isbn=978-1-4358-9437-2|page=7|edition=1st|url=https://books.google.com/books?id=7rvLPx33GPgC&pg=PA7|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20161203190215/https://books.google.com/books?id=7rvLPx33GPgC&pg=PA7|archive-date=2016-12-03}}</ref> Lọ́pọ̀ ìgbà tí àìsàn yí bá kọlu ènìyàn, ó ma ń to wákàtí méjì sí ọjọ́ márùn ún kí àpẹẹrẹ rẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀ sí í farahàn lára ènìyàn. <ref name="CDC2015Pro3">{{cite web|title=Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals|url=https://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|publisher=[[Centers for Disease Control and Prevention]]|access-date=17 March 2015|date=January 6, 2015|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20150320052724/http://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|archive-date=20 March 2015}}</ref>

<ref name="CDC2015Pro3">{{cite web|title=Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals|url=https://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|publisher=[[Centers for Disease Control and Prevention]]|access-date=17 March 2015|date=January 6, 2015|url-status=live|archive-url=https://web.archive.org/web/20150320052724/http://www.cdc.gov/cholera/healthprofessionals.html|archive-date=20 March 2015}}</ref>

Àtúnyẹ̀wò ní 22:47, 12 Oṣù Agẹmọ 2024


Àìsàn Kọ́lẹ́rà tabí Àìsàn onígbáméjì ( /ˈkɒlərə/) jẹ́ àrùn tàbí àìsàn tí ó ma ń ràn tí ó lè kọlu ènìyàn nígbà tí kòkòrò àrùn baktéríà kan tí wọ́n ń pè ní Vibrio cholerae bá kọlu ìfun kékeré tí ó ń gba Oúnjẹ dúró lára ènìyàn.[1][2] Àìsàn yí lè tètè farahàn lára eni tí ó bá mú tàbí kí ìfarahàn rẹ̀ mọ níwọ̀nba, bákan náà sì ni ìfarahàn àìsàn náà lè mú ọwọ́ èle pẹ̀lú.[3] Àmọ́, bí àìsàn yí bá mọ́wọ́ èle, aláàrẹ̀ náà yóò ma yàgbẹ́ gbuuru fún ọjọ́ mélòó kan. Bákan náà ni onítọ̀hún tún lè má a bì tí gbogbo inú rẹ̀ yóò sì má a lọ́ ọ jáì jáí.[3]èébì tàbí ìgbẹ́ aláàrẹ̀ náà báwá pọ̀ lápọ̀jù, èyí lè mú kí ipò tí omi wà nínú àgọ́ ara rẹ̀ ó dínkù kọjá ààlà, okun inú rẹ̀ kò sì ní gbé kánkán mọ́ láàrín wákàtí péréte tí ó fi ń bì tàbí ṣègbọ̀nsẹ̀. Ìgbọ̀nsẹ̀ gbuuru yíyà yí lè mú kí ojú aláàrẹ́ náà ó jìn wọnú láìpẹ́. Òtútù àbaadì lè ma mú u pẹ̀lú, iṣan ara rẹ̀ yóò ma lẹ, bákan náà ni àwọ̀ ara rẹ̀ yóò ma hunjọ pẹ̀lú. [4] Àìtó omi ara aláàrẹ̀ mọ́ yìí lè mú kí àwọ̀ rẹ̀ yí padà sí àwọ̀ búlúù.[5] Lọ́pọ̀ ìgbà tí àìsàn yí bá kọlu ènìyàn, ó ma ń to wákàtí méjì sí ọjọ́ márùn ún kí àpẹẹrẹ rẹ̀ tó bẹ̀rẹ̀ sí í farahàn lára ènìyàn. [6]

  1. Finkelstein, Richard A. (1996). "Cholera, Vibrio cholerae O1 and O139, and Other Pathogenic Vibrios". In Baron, Samuel. Medical Microbiology (4th ed.). University of Texas Medical Branch at Galveston. ISBN 978-0-9631172-1-2. PMID 21413330. Àdàkọ:NCBIBook2. 
  2. "Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals". Centers for Disease Control and Prevention. January 6, 2015. Archived from the original on 20 March 2015. Retrieved 17 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. 3.0 3.1 "Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals". Centers for Disease Control and Prevention. January 6, 2015. Archived from the original on 20 March 2015. Retrieved 17 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. "Cholera". Lancet 379 (9835): 2466–2476. June 2012. doi:10.1016/s0140-6736(12)60436-x. PMC 3761070. PMID 22748592. //www.pubmedcentral.nih.gov/articlerender.fcgi?tool=pmcentrez&artid=3761070. 
  5. Bailey, Diane (2011). Cholera (1st ed.). New York: Rosen Pub.. p. 7. ISBN 978-1-4358-9437-2. https://books.google.com/books?id=7rvLPx33GPgC&pg=PA7. 
  6. "Cholera – Vibrio cholerae infection Information for Public Health & Medical Professionals". Centers for Disease Control and Prevention. January 6, 2015. Archived from the original on 20 March 2015. Retrieved 17 March 2015.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)