Ìṣèlú: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
k Bot Títúnṣe: ckb:سیاسەت |
k Bot Fífikún: pnb:سیاست |
||
Ìlà 125: | Ìlà 125: | ||
[[pi:राज्यनीति]] |
[[pi:राज्यनीति]] |
||
[[pl:Polityka]] |
[[pl:Polityka]] |
||
[[pnb:سیاست]] |
|||
[[ps:سياست]] |
[[ps:سياست]] |
||
[[pt:Política]] |
[[pt:Política]] |
Àtúnyẹ̀wò ní 00:58, 4 Oṣù Agẹmọ 2010
Ìṣèlú tabi òṣèlú ni igbese bi awon idipo eniyan kan se n sepinnu. Oro yi je mimulo si iwuwa ninu awon ìjọba abele.
ÌSÈLÚ NILE YORUBA
Ní àwùjo Yorùbá, á ní àwon ònà ìsèlú tiwa tí ó dá wa yàtò sí èyà tàbí ìran mìíràn. Kí àwon Òyìnbó tó dé ní àwa Yorùbá ti ni ètò ìsèlú tiwa tí ó fesèmúlè. Tí ó sì wà láàárin òpò àwon ènìyàn. Yàtò sí tí àwon èyà bí i ti ìgbò tí ó jé wí pé àjorò ni won n fi ìjoba tiwon se (acephalous) tàbí ti Hausa níbi tí àse pípa wà lówó enìkan (centralization).
Ètò òsèlú Yorùbá bèrè láti inú ilé. Eyi si fi ipá tí àwon òbí ń kò nínú ilé se ìpìlè ètò òsèlú wa. Yorùbá bò won ní, “ilé là á tí kó èsó ròdé”. Baba tí ó jé olórí ilé ni ó jé olùdarí àkókó nínú ètò ìsèlú wa. Gbogbo èkó tó ye fún omo láti inú ilé ni yóò ti bèrè sí kó won. Bí i àwon èkó omolúàbí. Tí èdèàiyèdè bá selè nínú ile, bàbá ni yóò kókó parí rè. tí kò bá rí i yanjú ni yóò tó gbé e lo sí òdò mógàjí agbo-ilé. Agbo-ilé ni ìdílé bíi mérin lo sókè tó wà papò ni ojú kan náà. Won kó ilé won papò ní ààrin kan náà. Tí mógàjí bá mò ón tì, ó di odo olóyè àdúgbò. Olóyè yìí ni ó wà lórí àdúgbò. Àdúgbò ni àwon agbo-ilé orísìírísìí tí ó wà papò ní ojúkan. A tún máa ń rí àwon Baálè ìletò pàápàá tí wón jé asojú fún oba ìlú ní agbègbè won. Àwon ni òpá ìsàkóso abúlé yìí wà ní owó won. Ejó tí won kò bá rí ojúùtú sí ni wón máa ń gbé lo sí odo oba ìlú. Oba ni ó lágbára ju nínú àkàsò ìsàkóso ilè Yorùbá. Àwon Yorùbá ka àwon Oba won sí òrìsa Ìdí nìyí tí won fí máa ń so pé:
- Igba Irúmolè ojùkòtúu
- Igba Irúmolè ojùkòsì
Òkan tí ó lé nínú rè tí ó fi jé òkànlénú tàbí òkàn-lé-ní-rinwó (401), àwon oba ni. Won a ní.
KÁBÌYÈSÍ ALÁSE. ÈKEJÌ ÒRÌSÀ
Oba yìí ní àwon ìjòyè tí won jo ń sèlú. Ejó tí oba bá dá ni òpin. Ààfin oba ni ilé ejó tó ga jù. Oba a máa dájó ikú. Oba si le è gbésè lé ìyàwó tàbí ohun ìní elòmíì. Wón a ní: Oba kì í mùjè Ìyì ni oba ń fi orí bíbé se.
A rí àwon olóyè bí ìwàrèfà, ní òyó ni a ti ń pè wón ní Òyó-mèsì. Ìjòyè méfà tàbí méje ni won. Àwon ni afobaje. A rí àwon ìjòyè àdúgbò tàbí abúlé pàápàá tí ó máa ń bá oba se àpérò tàbí láti jábò ìlosíwájú agbègbè won fún un.
A tún ń àwon èsó tí ó ń dáàbò bo oba àti ìlú. Àwon ni won ń kojú ogun. Àwon ni o n lo gba isakole fóba. A tún ní àwon onífá, Babaláwo àti béè béè lo.
Ètò òsèlú wa tí ó fesè múlè yìí ni ó mú kí ó sòro fún àwon òyìnbó láti gàba tààrà lórí wa (Indirect rule). Àwon oba àti ìjòyè wa náà ni won ń lò láti sèjoba lórí wa. Ó pè díè kí wón tó rí wa wo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |