Jump to content

Ọlábísí Ọnàbánjọ: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
k Agbalagba ṣeyípòdà ojúewé Olóyè Bísí ỌnàbánjọỌlábísí Ọnàbánjọ
kNo edit summary
 
(Àwọn àtúnyẹ̀wò inú àrin 9 látọwọ́ àwọn oníṣe kò hàn)
Ìlà 14: Ìlà 14:
}}
}}


Olóyè '''Victor Ọlábísí Ọnàbánjọ''' ni wón bí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kejì ọduń 1927 tí ó sì papò dà ní ọjọ́ Kẹrìnlá oṣù Kẹrin ọdún 1990, jẹ́ gómìnà tẹ́lẹ̀ rí ní [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] ní àárín ọdún 1979 sí ọdún 1983, ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] nígbà ayé òṣèlú ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. <ref name="google">{{cite journal|title=West Africa|journal=West Africa : Africa's Weekly Magazine|date=1979|issue=nos. 3233-3258|publisher=Afrimedia International|issn=0043-2962|url=https://books.google.com/books?id=ezMOAQAAMAAJ|accessdate=2015-08-24}}</ref> He was of [[Ijebu people|Ijebu]] extraction.<ref>{{cite web|url=http://www.tribune.com.ng/21112009/analysis.html |title=Ogun 2011: Those Who Want OGD's Job |publisher=Saturday Tribune |date=21 November 2009 |accessdate=2009-12-17 |url-status=dead |archiveurl=https://web.archive.org/web/20091125121901/http://www.tribune.com.ng/21112009/analysis.html |archivedate=November 25, 2009 }}</ref>
[[Olóyè]] '''Victor Ọlábísí Ọnàbánjọ''' ni wón bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejì ọduń 1927, tí ó sì papò dà ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹ́rin ọdún 1990. Ó ti fìgbà kan jẹ́ [[gómìnà]] tẹ́lẹ̀ rí ní [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] ní àárín ọdún 1979 sí ọdún 1983, nígbà ayé òṣèlú ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]]. <ref name="google">{{cite journal|title=West Africa|journal=West Africa : Africa's Weekly Magazine|date=1979|issue=nos. 3233-3258|publisher=Afrimedia International|issn=0043-2962|url=https://books.google.com/books?id=ezMOAQAAMAAJ|accessdate=2015-08-24}}</ref> Bákan náà ni ó jẹ́ [[ọmọ]] ilu Ìpẹru Rẹ́mọ.<ref>{{cite web|url=http://www.tribune.com.ng/21112009/analysis.html |title=Ogun 2011: Those Who Want OGD's Job |publisher=Saturday Tribune |date=21 November 2009 |accessdate=2009-12-17 |url-status=dead |archiveurl=https://web.archive.org/web/20091125121901/http://www.tribune.com.ng/21112009/analysis.html |archivedate=November 25, 2009 }}</ref>


==Ìgbé ayé rẹ̀==
==Ìgbé ayé rẹ̀==
Wọ́n bí olóyè Victor Ọlábísí Ọnàbánjọ ní ọdún 1927 ní [[Ìpínlẹ̀ Èkó]]. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Onítẹ̀bọmi ti [[Baptist Academy]], nígbà tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ [[University of Westminster|Regent Street Polytechnic]] ní orílẹ̀-èdè [[Brítènì]], níbi tí ó ti kọ́ ìmọ̀ nípa ìròyìn àti ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ láàrín ọdún 1950 sí ọdún 1951. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí oníròyìn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ṣáájú kí ó tó padà di olóṣèlú pọ́nbélé.
Wọ́n bí olóyè Victor Ọlábísí Ọnàbánjọ ní ọdún 1927 ní [[Ìpínlẹ̀ Èkó]]. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Onítẹ̀bọmi ti [[Baptist Academy]], nígbà tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ [[University of Westminster|Regent Street Polytechnic]] ní orílẹ̀-èdè [[Brítènì]], níbi tí ó ti kọ́ ìmọ̀ nípa ìròyìn àti ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ láàrín ọdún 1950 sí ọdún 1951. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí oníròyìn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ṣáájú kí ó tó padà di olóṣèlú pọ́nbélé.
Ọnàbánjọ ma ń sọ àwọn òrọ̀ tí ó jẹ́ òtítọ́ nínú àlàfo [[Ìwé Ìròyìn]] olójoojúmọ́ ti ''Daily Service àti Daily Express'' níbi tí ó ti ma ń pe àkọ́lé ọ̀rọ̀ rẹ̀ ní "Ayékòótọ́'' láàrín ọdún 1954 sí ọdún 1962.<ref name=bookbio>{{cite web|url=http://www.afbis.com/store/system/index.html|title=Aiyekooto|publisher=AfBIS|accessdate=2009-12-17}}</ref>
Ọnàbánjọ ma ń sọ àwọn òrọ̀ tí ó jẹ́ òtítọ́ nínú àlàfo [[Ìwé Ìròyìn]] olójoojúmọ́ ti ''Daily Service àti Daily Express'' níbi tí ó ti ma ń pe àkọ́lé ọ̀rọ̀ rẹ̀ ní "Ayékòótọ́'' láàrín ọdún 1954 sí ọdún 1962.<ref name=bookbio>{{cite web|url=http://www.afbis.com/store/system/index.html|title=Aiyekooto|publisher=AfBIS|accessdate=2009-12-17|archive-date=2009-04-18|archive-url=https://web.archive.org/web/20090418013157/http://www.afbis.com/store/system/index.html|dead-url=yes}}</ref>


==Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olóṣèlú==
==Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olóṣèlú==


Wọ́n yan Ọlábísí gẹ́gẹ́ alága [[Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìjẹ̀bú-Òde]], ní ọdún 1977 lábẹ́ ọ̀gá rẹ̀ olóyè [[Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀]]. Lẹ́yìn tí ó kúrò ní ipò alága ìjọba ìbílẹ̀ yí tán ni wọ́n yàn án sípò [[Gómìnà]] ti [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] ní inú oṣù Kẹwàá ọdún 1979 lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú [[Unity Party of Nigeria]].<ref name=bookbio/>
Wọ́n yan Ọlábísí gẹ́gẹ́ sí ipò alága [[Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìjẹ̀bú-Òde]], ní ọdún 1977 lábẹ́ ọ̀gá rẹ̀ olóyè [[Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀]]. Lẹ́yìn tí ó kúrò ní ipò alága ìjọba ìbílẹ̀ yí tán ni wọ́n tú́n yàn án sípò [[Gómìnà]] ti [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] ní inú oṣù kẹwàá ọdún 1979 lábẹ́ ẹgbẹ́ ìṣèlú [[Unity Party of Nigeria]].<ref name=bookbio/>


Ọlábísí ṣe ìfilọ́ọ́lẹ̀ [[Ilé-iṣẹ́ amóhùnmáwòrán]] ti [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Karùn ún ọdún 1982. <ref>{{cite web|url=http://www.gamji.com/article4000/NEWS4651.htm
Ọlábísí ṣe ìfilọ́ọ́lẹ̀ [[Ilé-iṣẹ́ amóhùnmáwòrán]] ti [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Karùn ún ọdún 1982. <ref>{{cite web|url=http://www.gamji.com/article4000/NEWS4651.htm
|title=Gateway Television: Name- Change And Politics Of Envy|author=Tayo Agunbiade|publisher=Gamji
|title=Gateway Television: Name- Change And Politics Of Envy|author=Tayo Agunbiade|publisher=Gamji
|accessdate=2009-12-17}}</ref>
|accessdate=2009-12-17}}</ref>
Ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì ti [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] tí wọ́n dá sílè ní ọjọ́ Keje oṣù Keje ọdún 1982 ni wọ́n yí orúkọ rẹ̀ padà sí [[Yunifásitì Ọlábísí Ọnàbánjọ ]] ní ọjọ́ Kọkàndínlógún oṣù Karùn ún ọdún 2001 láti fi bu ọlá fún Olóyè Ọlábísí Ọnàbánjọ tí ó ti di olóògbé`.<ref>{{cite web |last1=Admin |title=OOU History |url=https://oouagoiwoye.edu.ng/history-of-the-university/ |website=OOU |accessdate=27 January 2019}}</ref>
Ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì ti [[Ìpínlẹ̀ Ògùn]] tí wọ́n dá sílè ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1982 ni wọ́n yí orúkọ rẹ̀ padà sí [[Yunifásitì Ọlábísí Ọnàbánjọ ]] ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù karùn ún ọdún 2001 láti fi bu ọlá fún [[Olóyè]] Ọlábísí Ọnàbánjọ tí ó ti di olóògbé`.<ref>{{cite web |last1=Admin |title=OOU History |url=https://oouagoiwoye.edu.ng/history-of-the-university/ |website=OOU |accessdate=27 January 2019}}</ref>
Olóyè Ọlábísí Ọnàbánjọ ni ó ṣe àgbékalẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ [[Abraham Adésànyà Polytechnic]], àmọ́ Ọ̀gágun [[Ọládípọ̀ Díyà]] tí ó jẹ́ gónìmà lábẹ́ ìṣàkóso [[Ìjọba Ológun]] fagilé ilé-ẹ̀kọ́ náà, wọ́n sì ṣí ilé-ẹ̀kọ́ náà padà nígbà tí ìṣèjọba àwa ara wa padà sí orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] ní ọdún 1999.<ref>{{cite news
Olóyè Ọlábísí Ọnàbánjọ ni ó ṣe àgbékalẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ [[Abraham Adésànyà Polytechnic]], àmọ́ Ọ̀gágun [[Ọládípọ̀ Díyà]] tí ó jẹ́ gónìmà lábẹ́ ìṣàkóso [[Ìjọba Ológun]] fagilé ilé-ẹ̀kọ́ náà, wọ́n sì ṣí ilé-ẹ̀kọ́ náà padà nígbà tí ìṣèjọba pààrọ̀ [[ọwọ́]] kúrò ni tológun sí ti àwa ara wa orílẹ̀-èdè [[Nàìjíríà]] ní ọdún 1999.<ref>{{cite news
|url=http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/featurettes/2009/june/15/Featurettes-06-15-2009-001.htm
|url=http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/featurettes/2009/june/15/Featurettes-06-15-2009-001.htm
|title=When fresh breeze blew on Adesanya Poly
|title=When fresh breeze blew on Adesanya Poly
Ìlà 35: Ìlà 35:
|publisher=Daily Sun
|publisher=Daily Sun
|accessdate=2009-12-17}}</ref>
|accessdate=2009-12-17}}</ref>
Lẹ́yìn ìfipá gbàjọba tí ó gbé ọ̀gágun [[Muhammadu Buhari]] dé orí ipò Ààrẹ apàṣẹ wàá, Buhari sọ Ọlábísí Ọnàbánjọ sí ẹ̀wọ̀n fún àìmọye ọdún.<ref>{{cite web
Lẹ́yìn ìfipá gbàjọba tí ó gbé ọ̀gágun [[Muhammadu Buhari]] dé orí ipò Ààrẹ apàṣẹ wàá, Buhari sọ Ọlábísí Ọnàbánjọ sí [[ẹ̀wọ̀n]] ọdún méjìlélógún, tí wọ́n sì da sílẹ̀ ní ọdún 1985 lábẹ́ ìṣèjọba ọ̀gágun [[Ibrahim Babangida]] tí ó bojú àánú wòó. Ọ̀gágun Ibrahim Babangida ni ó sì tún ṣètò bí ó ṣe padà lọ sí ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì láti lọ ṣètọ́jú ara rẹ̀. <ref>{{cite web
|url=http://thenationonlineng.net/web2/articles/18354/1/Exit-Gani-1938-2009/Page1.html
|url=http://thenationonlineng.net/web2/articles/18354/1/Exit-Gani-1938-2009/Page1.html
|title=Exit Gani (1938-2009)
|title=Exit Gani (1938-2009)
|author=Olakunle Abimbola
|author=Olakunle Abimbola
Ìlà 42: Ìlà 42:
|publisher=The Nation
|publisher=The Nation
|accessdate=2009-12-17}}</ref>
|accessdate=2009-12-17}}</ref>
Lẹ́yìn tí wọ́n da sílẹ̀ kúrò ní ọgbà ẹ̀wọ̀n, Ó padà sí ẹnu iṣẹ́ ìròyìn rẹ̀ tí ó sì ń ṣàgbéjáde àwọn ìròyìn òdodo tí ó ti ń ṣe tẹ́lẹ̀ tí ó ní ''Ayékòótọ́'' nínú àlàfo ìwé-ìròyìn [[Nigerian Tribune]] láàrín ọdún 1987 sí 1989.
Lẹ́yìn tí wọ́n da sílẹ̀ kúrò ní ọgbà ẹ̀wọ̀n, Ó padà sí ẹnu iṣẹ́ ìròyìn rẹ̀ tí ó sì ń ṣàgbéjáde àwọn ìròyìn òdodo tí ó ti ń ṣe tẹ́lẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní ''Ayékòótọ́'' nínú àlàfo [[ìwé-ìròyìn]] [[Nigerian Tribune]] láàrín ọdún 1987 sí 1989.
Olóyè Ọnàbánjọ dágbére fáyé ní ọjọ́ Kẹrin oṣù Kẹrìnlá ọdún 1990.
Olóyè Ọnàbánjọ dágbére fáyé ní ọjọ́ kẹrinlá oṣù kẹrin ọdún 1990.<ref name="f442">{{cite web | title=How Babangida helped my family back to England | website=P.M. News | date=2015-11-05 | url=https://pmnewsnigeria.com/2015/11/05/how-babangida-helped-my-family-back-to-england-lucy-onabanjo/ | access-date=2024-07-14}}</ref>


==Ìwé Ìtọ́kàsí==
==Ìwé Ìtọ́kàsí==
Ìlà 59: Ìlà 59:


{{DEFAULTSORT:Onabanjo, Olabisi}}
{{DEFAULTSORT:Onabanjo, Olabisi}}
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1927]]
[[Category:1927 births]]
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́aláìsí ní 1990]]
[[Category:1990 deaths]]
[[Category:Unity Party of Nigeria politicians]]
[[Category:Unity Party of Nigeria politicians]]
[[Category:Governors of Ogun State]]
[[Category:Governors of Ogun State]]

Àtúnyẹ̀wò lọ́wọ́lọ́wọ́ ní 16:04, 16 Oṣù Agẹmọ 2024

Ọlábísí Ọnàbánjọ
Governor of Ogun State
In office
Oct 1979 – Dec 1983
AsíwájúHarris Eghagha
Arọ́pòỌládípọ̀ Díyà
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1927-02-12)Oṣù Kejì 12, 1927
Lagos, Nigeria
AláìsíApril 14, 1990(1990-04-14) (ọmọ ọdún 63)

Olóyè Victor Ọlábísí Ọnàbánjọ ni wón bí ní ọjọ́ kejìlá oṣù kejì ọduń 1927, tí ó sì papò dà ní ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹ́rin ọdún 1990. Ó ti fìgbà kan jẹ́ gómìnà tẹ́lẹ̀ rí ní Ìpínlẹ̀ Ògùn ní àárín ọdún 1979 sí ọdún 1983, nígbà ayé òṣèlú ẹlẹ́kejì ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. [1] Bákan náà ni ó jẹ́ ọmọ ilu Ìpẹru Rẹ́mọ.[2]

Wọ́n bí olóyè Victor Ọlábísí Ọnàbánjọ ní ọdún 1927 ní Ìpínlẹ̀ Èkó. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Onítẹ̀bọmi ti Baptist Academy, nígbà tí ó sì lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Regent Street Polytechnic ní orílẹ̀-èdè Brítènì, níbi tí ó ti kọ́ ìmọ̀ nípa ìròyìn àti ìgbóhùn-sáfẹ́fẹ́ láàrín ọdún 1950 sí ọdún 1951. Ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí oníròyìn fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún ṣáájú kí ó tó padà di olóṣèlú pọ́nbélé. Ọnàbánjọ ma ń sọ àwọn òrọ̀ tí ó jẹ́ òtítọ́ nínú àlàfo Ìwé Ìròyìn olójoojúmọ́ ti Daily Service àti Daily Express níbi tí ó ti ma ń pe àkọ́lé ọ̀rọ̀ rẹ̀ ní "Ayékòótọ́ láàrín ọdún 1954 sí ọdún 1962.[3]

Iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Olóṣèlú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n yan Ọlábísí gẹ́gẹ́ sí ipò alága Ìjọba Ìbílẹ̀ Ìjẹ̀bú-Òde, ní ọdún 1977 lábẹ́ ọ̀gá rẹ̀ olóyè Ọbáfẹ́mi Awólọ́wọ̀. Lẹ́yìn tí ó kúrò ní ipò alága ìjọba ìbílẹ̀ yí tán ni wọ́n tú́n yàn án sípò Gómìnà ti Ìpínlẹ̀ Ògùn ní inú oṣù kẹwàá ọdún 1979 lábẹ́ ẹgbẹ́ ìṣèlú Unity Party of Nigeria.[3]

Ọlábísí ṣe ìfilọ́ọ́lẹ̀ Ilé-iṣẹ́ amóhùnmáwòrán ti Ìpínlẹ̀ Ògùn ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù Karùn ún ọdún 1982. [4] Ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì ti Ìpínlẹ̀ Ògùn tí wọ́n dá sílè ní ọjọ́ keje oṣù keje ọdún 1982 ni wọ́n yí orúkọ rẹ̀ padà sí Yunifásitì Ọlábísí Ọnàbánjọ ní ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù karùn ún ọdún 2001 láti fi bu ọlá fún Olóyè Ọlábísí Ọnàbánjọ tí ó ti di olóògbé`.[5] Olóyè Ọlábísí Ọnàbánjọ ni ó ṣe àgbékalẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ Abraham Adésànyà Polytechnic, àmọ́ Ọ̀gágun Ọládípọ̀ Díyà tí ó jẹ́ gónìmà lábẹ́ ìṣàkóso Ìjọba Ológun fagilé ilé-ẹ̀kọ́ náà, wọ́n sì ṣí ilé-ẹ̀kọ́ náà padà nígbà tí ìṣèjọba pààrọ̀ ọwọ́ kúrò ni tológun sí ti àwa ara wa ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ní ọdún 1999.[6] Lẹ́yìn ìfipá gbàjọba tí ó gbé ọ̀gágun Muhammadu Buhari dé orí ipò Ààrẹ apàṣẹ wàá, Buhari sọ Ọlábísí Ọnàbánjọ sí ẹ̀wọ̀n ọdún méjìlélógún, tí wọ́n sì da sílẹ̀ ní ọdún 1985 lábẹ́ ìṣèjọba ọ̀gágun Ibrahim Babangida tí ó bojú àánú wòó. Ọ̀gágun Ibrahim Babangida ni ó sì tún ṣètò bí ó ṣe padà lọ sí ilẹ̀ gẹ̀ẹ́sì láti lọ ṣètọ́jú ara rẹ̀. [7] Lẹ́yìn tí wọ́n da sílẹ̀ kúrò ní ọgbà ẹ̀wọ̀n, Ó padà sí ẹnu iṣẹ́ ìròyìn rẹ̀ tí ó sì ń ṣàgbéjáde àwọn ìròyìn òdodo tí ó ti ń ṣe tẹ́lẹ̀ tí ó pe àkọ́lé rẹ̀ ní Ayékòótọ́ nínú àlàfo ìwé-ìròyìn Nigerian Tribune láàrín ọdún 1987 sí 1989. Olóyè Ọnàbánjọ dágbére fáyé ní ọjọ́ kẹrinlá oṣù kẹrin ọdún 1990.[8]

Ìwé Ìtọ́kàsí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Victor Olabisi Onabanjo (Edited by Felix A. Adenaike) (1991). Aiyekooto. Syndicated Communications Ltd, Ibadan. ISBN 978-31115-0-7. 

Àwọn Ìtọ́kàsí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "West Africa". West Africa : Africa's Weekly Magazine (Afrimedia International) (nos. 3233-3258). 1979. ISSN 0043-2962. https://books.google.com/books?id=ezMOAQAAMAAJ. Retrieved 2015-08-24. 
  2. "Ogun 2011: Those Who Want OGD's Job". Saturday Tribune. 21 November 2009. Archived from the original on November 25, 2009. Retrieved 2009-12-17.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. 3.0 3.1 "Aiyekooto". AfBIS. Archived from the original on 2009-04-18. Retrieved 2009-12-17. 
  4. Tayo Agunbiade. "Gateway Television: Name- Change And Politics Of Envy". Gamji. Retrieved 2009-12-17. 
  5. Admin. "OOU History". OOU. Retrieved 27 January 2019. 
  6. LUKMAN OLABIYI (June 15, 2009). "When fresh breeze blew on Adesanya Poly". Daily Sun. http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/featurettes/2009/june/15/Featurettes-06-15-2009-001.htm. Retrieved 2009-12-17. 
  7. Olakunle Abimbola (15 September 2009). "Exit Gani (1938-2009)". The Nation. Retrieved 2009-12-17. 
  8. "How Babangida helped my family back to England". P.M. News. 2015-11-05. Retrieved 2024-07-14.