Open Amẹ́ríkà 2012

(Àtúnjúwe láti 2012 US Open (tennis))

The Open Amẹ́ríkà 2012 ni idije tenis to sele lori papa oriile lile ita ni USTA Billie Jean King National Tennis Center ni Flushing Meadows Park, to wa ladugbo Queens, New York City, ni Amerika. O waye lati August 27 de September 10. [1]

Pápá ìṣeré bọ́ọ̀lù àfọwọ́gbá ní Flushing Meadows
Open Amẹ́ríkà 2012
Date:   August 27 – September 10
Edition:   132nd
Category:   Grand Slam (ITF)
Surface:   Hardcourt
Location:   New York City, USA
Àwọn Ayọrí
Àwọn Ọkùnrin Ẹnìkan
United Kingdom Andy Murray
Àwọn Obìnrin Ẹnìkan
Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Serena Williams
Men's Doubles
Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Bob Bryan / Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Mike Bryan
Women's Doubles
Itálíà Sara Errani / Itálíà Roberta Vinci
Mixed Doubles
Rọ́síà Ekaterina Makarova / Brasil Bruno Soares
Boys' Singles
Kánádà Filip Peliwo
Girls' Singles
Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Samantha Crawford
Boys' Doubles
United Kingdom Kyle Edmund / Pọ́rtúgàl Frederico Ferreira Silva
Girls' Doubles
Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Gabrielle Andrews / Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Taylor Townsend
Open Amẹ́ríkà
 < 2011 2013 > 
  1. "Federer, Djokovic, Nadal headline men's field". www.usopen.org. August 8, 2012. Retrieved August 14, 2012.